Thursday, August 24, 2017

OSHOLE TODAJU

OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO
LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi
Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon
nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao
wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu
sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa
ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE
si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO
olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo
nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro. !
Fun alaye Lori nkan miiran epe numba yii 08102365897

No comments:

Post a Comment